Lati le je ki awon
alani ri nnkan fi sodun kawon naa darĂ po mo awon eeyan yooku fun odun to n bo
lona naa soosi Treasure House of God to wa ni Quarry niluu Abeokuta ti seto
ebun repete lorisirisi fawon alaini fun ti ayeye odun keresimesi to n bo lona
yii.
Gege bi agbenuso feto
iroyin ijo naa Ogbeni Adeniyi Adeloye ti wi, O ni Pasito Senfuye to je
oludasile ijo naa lo sagbekale eto naa lodoodun ati pe won lo ti wIjo Treasure House of
God fee seto iranlowo fawon alaini fodun tuntun
Lati le je ki awon
alani ri nnkan fi sodun kawon naa darĂ po mo awon eeyan yooku fun odun to n bo
lona naa soosi Treasure House of God to wa ni Quarry niluu Abeokuta ti seto
ebun repete lorisirisi fawon alaini fun ti ayeye odun keresimesi to n bo lona
yii.
Gege bi agbenuso feto
iroyin ijo naa Ogbeni Adeniyi Adeloye ti wi, O ni Pasito Senfuye to je
oludasile ijo naa lo sagbekale eto naa lodoodun ati pe won lo ti wa ninu ilana
ti Ijo naa ti la sile latigba ti won ti da a sile.
Adeniyi so pe ona ara
ni eto fi fawon alaini lebun odun naa yoo gba waye lodun yi nitori pe kii se
awon alaini to wa ninu ijo naa ni eto todun yi wa fun, gbogbo awon alaini to wa
ninu ijo naa ati agbegbe e ni won yoo je anfaani e, to fi mo gbogbo awon
akoroyin to wa nipinle Ogun.
O tun so pe yato sawon
alaini to wa lagbegbe ijo naa, awon ti won ba rii pe atije ko rorun fun won
niluu Abeokuta, ipinle Ogun, to fi mo awon alaini lorileede Naijiria ni won yoo
tun je anfaani e bakan naa.
Adeniyi so pe kii se
pe won deede gbe eto naa kale, bi ko se iwa aanu ti oludasile ijo naa, Pasito
Senfuye to tun ti figba akowe owo agba tele nipinle Ogun ni lati maa fi ran
awpn eeyan lowo
Bee lo so pe Oludasile
ijo naa se awon nnkan won yii nipa ase Iwe mimo Bibeli lati maa fi ran awon
eeyan lowo.
Capt: Soosi House of
God
No comments:
Post a Comment