Ogbeni Tunji Egbetokun
to je olori ile igbimo asofin tele nipinle Ogun la gbo pe o ti sa kuro lorile
ede yii nitori bi won se lawon oloselu kan n lepa emi e nitori oselu to n bo
lona.
Okunrin to figba kan
wa ninu egbe PDP tele ko to darapo mo APC nibi to ti ba Gomina Amosun sise po
ni saa akoko ni won lawon agbenipa kan wa kaakiri ko to di pe ori ko yo.
Ohun ta gbo ni pe
latigba ti won Okunrin olori ile igbimo asofin tele naa ti fi odo Amosun sile
loo darapo mo Seneto Adeola Olamilekan topo mo si Yayi lati di gomina ni won
lawon ti n yo lenu.
Won ni Okunrin naa so
pe nitori oun rii pe emi oun atawon ebi oun ko de,ti won si fee ko awon sinu
ewu lo mu ki oun salo laidagbere
Egbetokun toun ati
Otunba Gbenga Daniel to je gomina tele nipinle Ogun jo fa surutu lakoko tiyen
sejoba eleekeji lowo lo ni se ni awon oloselu to wa lode naa hale mo oun pe
toun atebi oun ba ni emi awon lo,koun tete yera lodo Yayi lati di gomina
bi beeko nnkan ti ko lero ni yoo sele si.
A tun gbo pe bi won se
dunkoko mo Okunrin yii bee naa ni won se bee fun iyawo ni won ni olori ile
igbimo asofin naa se roo pe eni to ba wa laye lo n mu nomba,toun atawon ebi e
fi sa kuro lorile ede yii.
|
Click here to Reply, Reply
to all, or Forward
|
No comments:
Post a Comment