Yayi bawon oluko sajoyo odun won - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Thursday 5 October 2017

Yayi bawon oluko sajoyo odun won
 
Seneto Solomon Adeola topo mo si Yayi ti ki gbogbo awon oluko lagbaye ku oriire ayajo won ti se lonin in, o nipa ti won ko ti mu idagbasoke ati olaju bawon eeyan kaakiri orile ede agbaye.

Ninu atejade kan ti Oloye Kayode Odunaro to je oludamoran fun lori eto iroyin fi sita laaro yii lo ti ni oludije fun ipo gomina labe egbe oselu APC nipinle Ogun ti nu inu oun dun peluu awon oluko lagbaye naa.

O ni akori awon oluko odun yii to da lori ominira nipa ikoni ati ri ro awon oluko lagbara je eyi to n bawon oluko nipinle Ogun finra,ti ko je kawon tisa lominira fun ra won.

O so pe ko si to buruku bijoba ba se awon eto to ye fawon oluko peluu awon ipa ribiribi ti won ti ko lori idagbasoke lawujo.

Bakan naa ni Yayi tun fi kun ninu oro e peluu ileri pe gbogbo ona loun yoo fi maa satileyin fawon oluko nitori bi ko ba si ipile ti won fi le le to n je kawon eeyan nimo lori eko inu okunkun lawon eeyan ko ba wa lawujo.

O wa gba awon oluko nimoran lati maa sa ipa won lori eko,ki won ma se je ki imo won ku mo won lori.

No comments:

Post a Comment

Pages