Ojo lojo ti eje jade nidi mi nibi ti mo ti n sere loju agbo - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Saturday 14 October 2017

Ojo lojo ti eje jade nidi mi nibi ti mo ti n sere loju agbo


Okan lara awon gbajumo olorin juju to tun n je olorin emi nni Olujimi Oyewusi topo awon ololufe e mo si G Mighty ti so pe ojo manigbagbe foun lojo ti eje bere si nii yo nidi oun, ojo naa nise naa ti koko fee yo lemi oun.

G Mighty
O soro yii lakoko to n ba oniroyin wa soro niluu Abeokuta lori ibi rise. naa gbe de,ati bo se di ilu mon on ka, o so pe oun ko mo pe oun si le wa laye di oni yii.

Gege bo se so, okan lara awon OPC to je gomina won lawon loo sere fun,bawon ti fee bere ere ni ojo n ro,sibe awon n ba ere won loo iyalenu lo je foun pe bi won se fee maa nawo foun loun sakiyesi pe eje n jade lati idi oun wa si sale.

O so pe" Ere ni mo ko pe nigba naa, nigba ti mo n tutu bi mo se sewo si okan lara aburo oun toun naa korin, iyen lo pari ere naa, p niye ojo ti mo lo ni osibitu."

O tun so pe leyin to n gbadun tan lawon OPC yen wa n beere lowo oun pe ki loun fori kan toun fi lagbara, nitori ka ni elomon in ni enu leje yen yoo ti maa jabo, ko si ni yes.

G Mighty tun salaye pe aimoye igba lawon maa n loo si ode ere to je pe awon omoota lo maa n gbowo lowo awon, ti won yoo tun maa pin fawon tawon sere iyen igba tawon ko tii loruko.

Gbogbo awon nnkan yen lo ti koko fee yoo ere lokan oun koun si pada sise gerungerun toun se amo awon eeyan lo gba oun lamorsn lati maa se fi sile.

Awpn meta lp pe gege bi awpkose e nidi ise orin juju awon naa ni Oloye Ebeneezer Obey King Sunny Ade ati Yinka Ayefele. O ni bo tile je pe oun ko kose naa labe enikankan sugbon Baba oun ni won je.

Bakan naa lo tun so pe aimoye kaseeti loun tii bawon sise po sugbon meji loun ti se jade to si n ta nita titi di akoko yii awon naa ni Arise and Shine ati Greater Grace, bee lo ni awon tun ti se kaseeti fawon oloselu.

Lara awon to so pe awon jo jegbe nidi ise Juju ni Wole Papa,Alayo Melody, Adasi atawon min in. O wa ni kawon ololufe e maa reti kaseeti tuntun to pe ni uncommon favour.


No comments:

Post a Comment

Pages