Ariwajoye fee gbe Ewi Apero jade - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 3 October 2017

Ariwajoye fee gbe Ewi Apero jadeBi nnkan se n loo, bo se n loo yii laipe yii ni gbajumo akewi nni Bayo Oyebamji topo awpn eeyan mo si Ariwajoye yoo gbe ewi tuntun kan jade eyi to pe ni Apero

Gege bi atejade to te BO SE Ri lowo, ewi naa ni okunrin yii ti so hulehule awon nnkan to ti sele lori lede yii lati Ibere pepe ti di akoko yii.

A gbo pe laipe yii ni won ya fidio ewi naa, eyi ti yoo di agbelewo laipe yii, nigba to n ba oniroyin wa soro, Ogbeni Bayo Oyebamji so pe ohun gbe ewi naa kale lati je ki gbogbo wa fi gbodo sapero lori bi idagbasoke yoo se de ba orile ede yii.

Bakan lo lawon tun menuba IPA tawon oloogun ti ko lorile ede yii ati ibi ti won ba wa de,  p ni kaseeti ewi teeyan gbodo toju pamo dojo iwaju ni,nitori awon nnkan tawon po po nibe ko se lafiwe.

Ninu oro Ogbeni Adebayo Ojo topo mo si Mista Vim to je amugbalegbe akewi naa, o ni o gba Ariwajoye to kewi naa laimoye odun ko to sagbekale ewi naa,nitori awon ise iwadii abenu to se.

O ni akoko ko re ti okunrin naa yoo ti maa gbe ewi jade ati pe eyi to se gbeyin to pe ni Tifun tedo si n loo lowo.

No comments:

Post a Comment

Pages