Gọngọ sọ nibi ayẹyẹ ikomọjade ọba Oniba Eko - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 17 October 2023

Gọngọ sọ nibi ayẹyẹ ikomọjade ọba Oniba Eko

   Ọmọọba Jamiu  Ademoye

 Oba Sulaimon Adeshina Raji-Ashade , Oniba Ekun ti ilu iba, fi idunnu han si gbogbo si  gbogbo awon alejo pataki pataki ti won ba a se ajoyo ikomo tuntun ti iyawo ẹ, Olori Muslimot Sulaimon Raji-Ashade bi fun un.

Oniwaasi agbaaye  nni, Sheik Muyideen Ajani Bello, lo waasu lọjọ pe naa nibẹ  lop ti sọ nipa awọn ohun idagbasoke ti ọba naa ti mu bai ilu t Ọba.

Ninu waasi ẹ, Alh. Muyideen so bi Olorun Oba se ma n dara fun eda nipa eto ọmọ bibi. O ba Oniba dupe fun ti ajoyo ọmọ tuntun, pẹlu adura pe ki Ọlọrun fun un ni ẹmi gungun ati alaafia lati fi tọju ọmọ naa.

Bẹẹ loọ́ tun se adura fun lya ọmo naa ati ilu lba, Eko ati Orile ede Naijiria lapapo.
 
Orukọ ti wọn sọ ọmọ naa ni Muh. Qazim  Abisade, Adebowale, Akanni, Adedimeta, Desire, Adeyinka, ( Ati opolopo oruko abiso) Sulaimon Adeshina Raji-Ashade

.
 Oludari eto ijoko, ilu mooka oniroyin, Abd'Fatai Abd'Gafar naa menu ba onirunru agbega ati igba otun to deba ilu iba nipa eto ilera ( Health centre) , Gbogan Ero ayara bi asa ( ICT Centre) , ati nipa awon eeyan patakipataki ti won ti wasi ilu iba nipase Oniba Ekun.

Leyin isomo loruko ni wejewemu waye. Awon ladelade polo Jara, lara won latiri : Oba Moruf Ojoola ( Ojon ti Ejigbo) ,Oba Kabiru ( Osolo ti ilu lsolo) ,Oba Hamed Orelope-Laka ( Elegbeda) , Oba Akibu ( Orisunbare) , Oba Oloto, Onijankin, 


Nikale la tun ti ri, Oba Saheed ( Idi Oke ) Onigboko,  , Oba Elekunpa , ati beebee lo.

: Awon Baale naa kogbeyin, Baba Oba ilu iba, Hon. Chief Suarau, Baale ije dodo, chief Jelili ati awon saraki saraki lawujo. 

No comments:

Post a Comment

Pages