Ile ti mo ko si Ibadan, mo fi mu Inu awon obi mi dun ni- Abass Obesere - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Monday 20 February 2023

Ile ti mo ko si Ibadan, mo fi mu Inu awon obi mi dun ni- Abass Obesere




Ko si eni to ri Ile olowo nla ti agba osere onifuji nni, Abass Akande Obesere, ko si ilu Ibadan, ti ko nii ku aje ku ikale, ti won ko si nii kan sara sii pelu.

Gege bi a se gbo,Ile naa ti won ti si ni gbajumo onifuji naa ko si agboole Ajalaruru, ni won lo pe nile molebi ati pe oun gbe igbese naa lati fi mu Inu awon obi oun dun.

O so pe ohun to se pataki fun omo ni lati maa mu Inu won dun nigba ti won ba wa laye ati ti won ba papoda.

Abass tun salaye pe gege bi awon eeyan se mo pe omo Ile Ajalaruru loun niluu Ibadan, agboole naa lo si se fowo to seyin niluu Ibadan fáwọn ipa ribiribi ti won ti lo.

O waa lo akoko naa lati fi dupe lowo gbogbo awon to wa baa se ajoyo mo mi n mo ti omo e, Cyinthia to se laipe yii. 

Bee lo tun se adura pe ajosepo laarin oun atawon ololoolufe oun ko nii baje

No comments:

Post a Comment

Pages