E ranti ojo ola awon omo yin ki e to dibo lojo Satide - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Thursday 23 February 2023

E ranti ojo ola awon omo yin ki e to dibo lojo SatideOgbeni  Wasiu Aremu, oga oniroyin to nileese telifisan1steleven9jatv.com, to tun je oludasile ileeese AREMS Entertainment, ti ro awon araalu lati to tawon omo won idibo ti won fee di lojo Satide, ose yii.

Gege bi atejade kan to fi sita ni ale yii to pe akole e ni ojo Satide mi ibo aare, n je ti mo awon oludije.

O so pe ko to di pe e fee lo dibo fun eni to wu yin ti okan yin so pe ki e dibo fun, e ma se Tori eelo kan dibo naa


O so pe, "Awon nnkan ti mo fee ki e ma ro mi pe eelo mi won fe ra Ibo yin?,nje owo naa lo to yin na fun odun merin si mejo
Bawo le se fe ki tawon omo atawon ebi yin ti?

O waa gba awon eeyan nimoran pe ki to di pe won dibo, ki won too leemeji, ki won si ranti ojo ola awon omo won ati eyi ti won lo ti bi.

O ni ki won jade dibo daadaa pelu kaadi idibo PVC won lati le yan asaaju rere.


No comments:

Post a Comment

Pages