Egbe oselu ADC yoo bere ipologo lola - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 31 January 2023

Egbe oselu ADC yoo bere ipologo lola



Lola, tii se ojo kin in ni, osu keji ni egbe oselu ADC, ti ipinle Ogun, yoo bere ipolongo won fun ti idibo to n bo.

Gege bi a se, Ake, niluu Abeokuta mi eto naa yoo bere, nibi ti Agbejoro Biyi Otegbeye, oludije gomina labe egbe oselu naa yoo ti saaju awon oludije yooku wa sibe.

 Opo awon alatileyin egbe naa ni won n bo lojo naa.Bakan naa la gbo pe gbogbo ijoba ibile Ogun to wa nipinle Ogun, ni won yoo gbe ipongo won de.

Bo tile je pe o ti ye ki ipolongo naa ti bere tipe sugbon nitori ejo kotemilorun ti won sese gba idande lo mi faa seyin die.

No comments:

Post a Comment

Pages