Ojoojumo ni irawo Saheed Osupa tan kaakiri aye- Arems - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Monday 26 December 2022

Ojoojumo ni irawo Saheed Osupa tan kaakiri aye- Arems




Oludasile ileese telifisan 1stEleven9jaTV, Wasiu Aremu Adeniyi, topo awon oloolufe mo si  Arems, ti awon asiiri nla kan idi ti gbajumo onifuji nni, Alaaji Saheed Akorede Okunola , topo mo si Saheed Osupa se n fojoomo gbayi si nidii ise orin amuludun, eyi tawon oloyinbo pe ni Greatest Of All Time, G.O.A.

Osupa tawon eeyan tun pe ni G.O.A.T, tun fi ara  e han pe loooto kariaye ni  osupa oun yo lojoojumo, ninu awo orin to sese fee gbe jade to pe akole e ni
 "Fuji Template,"ti yoo jade ni otunla, Wesidee, ojo kejidinlogbon, osu yii, ti yoo tun mi gbogbo ilu titi. 

Arems salaye siwaju pe oore ofe toun ni lati fi gbo orin naa tun je ki oun mo pe ko si elegbe irawo oseere onifuji yii ninu ki a fi opolo gbe orin jade. 


Bee lo tun so pe Saheed Osupa si ni olorin to ba igba mu tawon araye n fe lojoojumo, nitori awon ewa ede Yoruba to fi sagbekale awo orin tuntun naa. 
.
A o ranti pe laarin odun yii ni Oba orin 
 Saheed Osupa, rin irinajo lo si orileede Amerika nibi to ti gbayi gbeye bo tawon oyinbo naa kan sara si i. 

Bakan lo tun ni Oba orin, nikan to tun kopa ninu ere tiata ati orin igbalode hip fuji nikan ni onifuji ti ise orin ti mu gba awoodu kaakiri agbaye. 
.


No comments:

Post a Comment

Pages