Agbejoro Biyi Otegbeye, oludije gomina labe egbe oselu ADC nipinle Ogun, ti ranse ikinni ku oriire si Dokita Akinde, Mukail Aremu, gege bi oga agba tuntun fun ileewe giga poli, tiluu Ilaro, eyi ti Aare orileede yii, Muhammadu Buhari, yan an si.
Ninu atejade ti oludije naa fi sita, lo ti salaye oga agba naa bi eni to ti n farajin tipe, idi niyi toun ko fi le siyemeji fun ipo tuntun ti won yan an si yii, nitori akoni ti ko fise e sere ni
Biyi Otegbeye tun so pe"" Oga agba tuntun yii je eni to koju osuwon lati le sakoso ileewe giga tijoba apapo Poli, Ilaro, to je okan gboogi ni Ogun West nitori awon iriri to ti ni".
O waa gbadura pe ki Olorun maa dari e ninu ohun gbogbo to ba n se, ko si le se aseyori.
No comments:
Post a Comment