Egbe
awon onikeke Tricycle Owners Association tawon eeyan mo si TOAN tie ka tipinle
Ogun ti won foruko sile labe Trade Union Congress, TUC ti ke si ileese ti n pawo
wole nipinle naa lati gba won laye lati maa ta iwe ori keke fawon omo egbe won.
Atejade
yii waye nibi apileko abajade egbe naa ti won fi sita nibi ti won ti safikun
awon oloye egbe won, eyi to waye lojo Et, Furaide, ose to koja.
Bakan
naa lawon omo egbe naa tun fatleyin won han lori ilakaka awon oloye egbe naa
labe alaga won, Komureedi Tirisimiyu Muraino, lori bi won se mu ise won ni Pataki
lati mu ipolongo ba egbe won
Bee
legbe awon onikeke TOAN tun lo akoko naa lati so pe awon ko nigbagbo ninu
okunrin kan ti won n pe ni.Kehinde Talibu, ti inagije n je Baba Eba atawon
eeyan e kan lori bi won se ni won dite, pelu amoran pe ki won tun ero won pa,
ki alaafia tun le joba.
Ninu atejade wonyii ni won tun ti ki Omooba
Dapo Abiodun ku oriire gege bi gomina tuntun nipinle Ogun, pelu ileri pe awon
setan lati sise po pelu e lati mu ipinle naa goke agba
Awon
to wa nibi ipade naa ni alaga egbe naa Komueedi Tirisimiyu Muraino atawon
igbimo agba egbe naa to fi mo iya isale won, Arabinrin Juliana Oladimeji, Oloye
Isiaka Olutola ati Onarebu Dele Sobaloju.
No comments:
Post a Comment