Omooba
Rotimi Paseda to je oludije fun ipo gomina labe egbe oselu UPN ti gba ijoba
apapo nimoran lati kede eto eko pajawiri kaakiri orile ede yiii.
Lojooru
Wesde ose yii ni okunrin naa soro yii ni Ijebu Ode lakoko to n se abewo sawon
omo ileewe ti won jafaani eko ofe lakoko isinmi ti won wa,eyi ajo Paseda Legacy
sagbateru e.
O
bu enu ate lu nijoba ipinle Ogun ko se fi bee nawo lori eto eko peluu gbogbo
ariwo owo nla ti won maa lawon la sile fun eto naa, o ni o je okan lara awon
nnkan to je ki ina eto eko naa jo ajoreyin.
Gege
bo se wi, o ni ka ni nijoba ipinle Ogun ba n kowo lori eto eko bo se ye ni yoo
tun ti ran oro aje wa lowo ju bayii loo.
Paseda
wa so di mimo pe eko ofe lakoko isinmi to sagbateru e ko ni nnkan se peluu
oselu sugbon lati fu adun fawon Iran to n bo lojo iwaju.
Olunrin
naa tun wa so bi ipinle Ogun naa se loo se iru eto eko ofe isinmi naa leyin ti
won ri eyi toum da sile yii. O ni eyi tijoba se nibi tawon omoleewe ti
won ko to igba ti n kopa lowo je eyi t ko fi bee dara to, nitori obi ti ko ba
lowo ko le kopa nibe, o lo yato seyi tawon se fawon omo lofe.
Okunrin
naa so pe bo tile je pe awon omode atawon agba ti ba ijakule pade lowo ijoba to
wa lode yii sugbon sa, eto eko ofe to m loo lowo yii yoo maa te siwaju titi di
odun 2019.
O
wa ro awon elegbejegbe lati Kopa pataki fun aseyori eto eko lorile ede yii
nitori okan lara awon ohun amuyangan ni.
Eto
eko ofe isinmi ti ajo Paseda Legacy sagbateru e yii la gbo pe awon omoleewe bi
egberun mewaa ti kopa ninu e laarin lawon ijoba ibile Ogun to wa nipinle Ogun
No comments:
Post a Comment