Mayegun fẹẹ ṣayẹyẹ ọjọọbi aadọrin ọdun lara ọtọ - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Saturday 3 August 2024

Mayegun fẹẹ ṣayẹyẹ ọjọọbi aadọrin ọdun lara ọtọ



Gbogbo eto lo ti to fun ayẹyẹ ọjọọbi aadọrin ọdun ti Oloye Musẹdinku Alao Onimọlẹ Mayegun.

Gẹgẹ bi ṣe gbọ, ọjọ kẹfa, oṣu kẹjọ ni ariya rẹpẹtẹ fun ọjọọbi ọhun yoo waye nile ẹ ni Agọ ka, niluu Abẹokuta 

Ohun taa gbọ ni pe adura yoo wa laaarọ kutu ọjọ naa ko to di pe faaji yoo bẹrẹ nibi tawọn eeyan yoo ti wẹjẹ wẹmu pẹlu wọn.

Awọn ọtọkulu ilu si ti n ki Mayegun ku imurasilẹ ọjọọbi ọhun pẹlu adura pe ko nii fi eyi ṣe aṣemọ.

No comments:

Post a Comment

Pages