Ẹgbẹ apapọ oṣelu nipinlẹ Ogun iyẹn Inter-Party Advisory Council IPAC, ti Kọmureedi Abayọmi Sanyaolu jẹ alaga wọn ti gbe igbimọ oriṣi mẹsan-an kan dide fun ilọsiwaju ati mudunmudun ijọba dẹmokiresi nipinlẹ ọhun.
Ninu atẹjade ti wọn fi sita laarin ọsẹ to kọja yii ni wọn ti rọ awọn igbimọ naa lati jọ ṣiṣẹ pọ ki igbọra ẹni ye fi le wa laarin wọn bẹẹ ni ki wọn si tun gba ifẹ laaye.
Wọn ni yiyan awọn igbimọ naa wa lara ilana ati ofin ẹgbẹ apapọ oṣelu IPAC, lati le jẹ ki gbogbo awọn ẹgbẹ oṣelu kọọkan nipa kan tabi meji ko fun ilọsiwaju wọn.
Bẹẹ la gbọ pe ko si ẹgbẹ oṣelu kan nipinlẹ naa ti ko si ninu igbimọ ọhun pẹlu ẹka ibi ti wọn yoo ti ṣiṣẹ.
Awọn igbimọ ọhun ni
No comments:
Post a Comment