Ẹlẹmide di olori ile igbimọ aṣofin tuntun nipinlẹ Ogun - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 23 January 2024

Ẹlẹmide di olori ile igbimọ aṣofin tuntun nipinlẹ Ogun



Ile igbimọ aṣofin nipinlẹ Ogun ti yọ olori ile igbimọ aṣofin wọn, Ọnarebu Taiwo Olukunle Oluọmọ kuro, wọn si ti fi Oludaisi Ẹlẹmide lati ẹkun Ọdẹda rọpo.

Iyọnipo yii waye lakooko ti wọn ṣe ijokoo ipade wọn lonii, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee.
Gẹgẹ bi a ṣẹ gbọ, awọn ọmọ ile igbimọ aṣofin mejiidinlogun ni wọn fọwọ si yiyọ olori ile igbimọ aṣofin tẹlẹ naa
Bẹẹ ni wọn sọ pe ọkunrin naa ko yọju rara nibi ijokoo naa.

No comments:

Post a Comment

Pages