Wolii Ogundipe Genesis ni odun ayo lodun yii yoo je fun mutumuwa - BO SE RI

Breaking

Coco Samba

Coco Samba
Coco Samba

Tuesday 3 January 2023

Wolii Ogundipe Genesis ni odun ayo lodun yii yoo je fun mutumuwa
Wolii Israel Oladele Ogundipe tijo Genesis lagbaaye ti muu da gbogbo omo orileeede yii loju pe odun taa sese mu naa yoo je ireti tuntun sinu ogo, ayo, abayori ohun rere ati ipile rere. 

Ojise Olorun soro naa fun ise odun to ran si gbogbo omo orileede  yii. O ki won ku oriire pe Olorun tun kawon ye gege bi eni to ri odun 2023.

O salaye siwaju pe pelu idunnu ati ayo lo n fi ki awon eeyan wonu odun naa. Bee lo tun so fawon oniroyin pe ko ya oun lenu pe gbogbo wa sajoyo ibere odun naa ni ayo ati alaafia pelu awon eeyan wa. O wa gbadura fun alaafia lorileede yii fun ti ibo to n bo lona. 

.

No comments:

Post a Comment

Pages