Odoodun la n ri orogbo
Odoodun la n ri awusa
Odoodun la n ri omo obi lo ri ate
Olubiyi omo Otegbeye o ku ayeye odun kadun ojo tonii
Waa se opo odun laye
Igba odun, odun kan ni
E ku oriire tonii, iwoyi odun to m bo Oke-Mosan
La o ti se gege bi gomina ipinle Ogun.
No comments:
Post a Comment